-
Notifications
You must be signed in to change notification settings - Fork 37
/
Copy pathemoji-yo.json
3676 lines (3676 loc) · 191 KB
/
emoji-yo.json
1
2
3
4
5
6
7
8
9
10
11
12
13
14
15
16
17
18
19
20
21
22
23
24
25
26
27
28
29
30
31
32
33
34
35
36
37
38
39
40
41
42
43
44
45
46
47
48
49
50
51
52
53
54
55
56
57
58
59
60
61
62
63
64
65
66
67
68
69
70
71
72
73
74
75
76
77
78
79
80
81
82
83
84
85
86
87
88
89
90
91
92
93
94
95
96
97
98
99
100
101
102
103
104
105
106
107
108
109
110
111
112
113
114
115
116
117
118
119
120
121
122
123
124
125
126
127
128
129
130
131
132
133
134
135
136
137
138
139
140
141
142
143
144
145
146
147
148
149
150
151
152
153
154
155
156
157
158
159
160
161
162
163
164
165
166
167
168
169
170
171
172
173
174
175
176
177
178
179
180
181
182
183
184
185
186
187
188
189
190
191
192
193
194
195
196
197
198
199
200
201
202
203
204
205
206
207
208
209
210
211
212
213
214
215
216
217
218
219
220
221
222
223
224
225
226
227
228
229
230
231
232
233
234
235
236
237
238
239
240
241
242
243
244
245
246
247
248
249
250
251
252
253
254
255
256
257
258
259
260
261
262
263
264
265
266
267
268
269
270
271
272
273
274
275
276
277
278
279
280
281
282
283
284
285
286
287
288
289
290
291
292
293
294
295
296
297
298
299
300
301
302
303
304
305
306
307
308
309
310
311
312
313
314
315
316
317
318
319
320
321
322
323
324
325
326
327
328
329
330
331
332
333
334
335
336
337
338
339
340
341
342
343
344
345
346
347
348
349
350
351
352
353
354
355
356
357
358
359
360
361
362
363
364
365
366
367
368
369
370
371
372
373
374
375
376
377
378
379
380
381
382
383
384
385
386
387
388
389
390
391
392
393
394
395
396
397
398
399
400
401
402
403
404
405
406
407
408
409
410
411
412
413
414
415
416
417
418
419
420
421
422
423
424
425
426
427
428
429
430
431
432
433
434
435
436
437
438
439
440
441
442
443
444
445
446
447
448
449
450
451
452
453
454
455
456
457
458
459
460
461
462
463
464
465
466
467
468
469
470
471
472
473
474
475
476
477
478
479
480
481
482
483
484
485
486
487
488
489
490
491
492
493
494
495
496
497
498
499
500
501
502
503
504
505
506
507
508
509
510
511
512
513
514
515
516
517
518
519
520
521
522
523
524
525
526
527
528
529
530
531
532
533
534
535
536
537
538
539
540
541
542
543
544
545
546
547
548
549
550
551
552
553
554
555
556
557
558
559
560
561
562
563
564
565
566
567
568
569
570
571
572
573
574
575
576
577
578
579
580
581
582
583
584
585
586
587
588
589
590
591
592
593
594
595
596
597
598
599
600
601
602
603
604
605
606
607
608
609
610
611
612
613
614
615
616
617
618
619
620
621
622
623
624
625
626
627
628
629
630
631
632
633
634
635
636
637
638
639
640
641
642
643
644
645
646
647
648
649
650
651
652
653
654
655
656
657
658
659
660
661
662
663
664
665
666
667
668
669
670
671
672
673
674
675
676
677
678
679
680
681
682
683
684
685
686
687
688
689
690
691
692
693
694
695
696
697
698
699
700
701
702
703
704
705
706
707
708
709
710
711
712
713
714
715
716
717
718
719
720
721
722
723
724
725
726
727
728
729
730
731
732
733
734
735
736
737
738
739
740
741
742
743
744
745
746
747
748
749
750
751
752
753
754
755
756
757
758
759
760
761
762
763
764
765
766
767
768
769
770
771
772
773
774
775
776
777
778
779
780
781
782
783
784
785
786
787
788
789
790
791
792
793
794
795
796
797
798
799
800
801
802
803
804
805
806
807
808
809
810
811
812
813
814
815
816
817
818
819
820
821
822
823
824
825
826
827
828
829
830
831
832
833
834
835
836
837
838
839
840
841
842
843
844
845
846
847
848
849
850
851
852
853
854
855
856
857
858
859
860
861
862
863
864
865
866
867
868
869
870
871
872
873
874
875
876
877
878
879
880
881
882
883
884
885
886
887
888
889
890
891
892
893
894
895
896
897
898
899
900
901
902
903
904
905
906
907
908
909
910
911
912
913
914
915
916
917
918
919
920
921
922
923
924
925
926
927
928
929
930
931
932
933
934
935
936
937
938
939
940
941
942
943
944
945
946
947
948
949
950
951
952
953
954
955
956
957
958
959
960
961
962
963
964
965
966
967
968
969
970
971
972
973
974
975
976
977
978
979
980
981
982
983
984
985
986
987
988
989
990
991
992
993
994
995
996
997
998
999
1000
{
"i506b710": "Àwọn amì ẹ̀rín músẹ́ àti àwọn èyàn",
"f457f732": "Ẹrankó àti ìṣẹ̀dá",
"ce9bf9a4": "Ohun jíjẹ àti mímu",
"da1e1fd2": "Ìṣé",
"g280553c": "Irin-àjò àti ibi",
"b2f95aa6": "Àwọn ohun rírí",
"ac91750e": "Àwọn àmì",
"j56c4be0": "Àwọn àsíá",
"ef15e12a": "Ojú tó nbóyín",
"g9d0571a": "ojú,bóyín,dunú",
"db5cfab4": "Ojú tó nrẹ́rìn músẹ́ tó sì la ẹnu sílẹ̀",
"aead588c": "ojú,ẹnu,ṣí,rẹ́rìn músẹ́,dunú",
"c29cc866": "Ojú tó nrẹ́rìn músẹ́ tó sì la ẹnu àti ojú sílẹ̀",
"db0d8f24": "ojú,ojú,ẹnu,ṣí,rẹ́rìn músẹ́,dunú",
"i2f5a850": "Ojú tó nbóyín pẹ̀lú ojú tó nrẹ́rín músẹ́",
"af2d51c8": "ojú,ojú,bóyín,rẹ́rìn músẹ́",
"f61c01c8": "Ojú tó nrẹ́rìn músẹ́ tó sì la ẹnu sílẹ̀ pẹ̀lú ojú tó padè pinpin",
"c64c70ce": "ojú, ẹ́rìn,ẹnu,ṣí,tẹ́lọ́rùn,rẹ́rin músẹ́",
"c6db198e": "Ojú tó nrẹ́rìn músẹ́ tó la ẹnu pẹ̀lú ìlàágùn",
"c36e8a34": "tutù,ojú,ṣí,rẹ́rìn músẹ́,làágùn",
"g03ce604": "Ojú tó ní omijé ayọ̀",
"ac782c22": "ojú,ayọ̀,rẹ́rìn,omijé",
"h02a0304": "Ǹ yí ní ilẹ̀ ó sì nrẹ́rìn",
"ie9be094": "ojú,ilẹ̀ẹ́lẹ̀,rẹ́rìn,rẹ́rìn síta,ǹ yí nílẹ̀ tó ń rẹ́rìn,ǹ yí nílẹ̀",
"a6f5cafe": "Ojú tó nrẹ́rìn músẹ́ pẹ̀lú ìmọ́lẹ̀ lórí",
"dda65ca0": "ángẹ́li,ojú,àlọ́,ìrònú asán,halo,kò mọ̀ nípa rẹ̀,rẹ́rìn músẹ́",
"d0d84b3e": "Ojú tó nṣẹ́jú",
"ce8aafca": "ojú,ṣẹ́jú",
"b3002876": "Ojú tó nrẹ́rìn músẹ́ pẹ̀lú ojú tó nrẹ́rìn",
"id0fe4dc": "ẹ̀rín ìtìjú,ojú,ojú,rẹ́rìn músẹ́",
"c5b1de4a": "Ojú tó nrẹ́rìń músẹ̀ díẹ̀",
"e58a4f9e": "ojú,rẹ́rìn músẹ́,dunú",
"j5ae69de": "Ojú tó doríkodò",
"e5863352": "ojú,ìdoríkodò",
"effe01ce": "Ojú tó nrẹ́rìn músẹ́",
"cdf66c26": "ojú,kọ jáde,simi,rẹ́rìn músẹ́",
"dfd282ac": "Ojú tó n gbádùn oúnjẹ́",
"c5f2ddac": "àjẹgbádùn,ojú,óúńjẹ tó jẹ́ kí ènìyàn ma datọ̀,um,yum",
"a94a48c8": "Ojú tó tura",
"ed446f6a": "ojú,tura",
"ee227fd0": "Ojú tó nrẹ́rin músẹ́ pẹ̀lú ojú tó dàbí ọkàn ",
"i3243a0a": "ojú,ojú,ọkàn,ìfẹ́,rẹ́rìn músẹ́",
"a8f73238": "Ojú tó n rẹ́rin pẹ̀lú ọkàn 3",
"i662dcdc": "ojú, ìfẹ́, fẹ́ràn,nífẹ̀ẹ́",
"f1ecacba": "Ojú tó ṣá ẹnu jẹ́",
"a47e5864": "ojú,ọkàn,fi ẹnu ko ẹnu",
"i0f913f0": "Ojú tó nfi ẹnu ko lẹ́nu",
"c8bf47cc": "ojú,fi ẹnu ko ẹnu",
"gdc9c2ac": "Ojú tó nfi ẹnu koni lẹ́nu pẹ̀lú ojú tó nrẹ́rìn",
"f0b096c2": "ojú, ojú,fi ẹnu ko ẹnu,rẹrìn músẹ́",
"bbe56712": "Ojú tó nnfi ẹnu koni lẹ́nu pẹ̀lú ojú pípadé",
"a5e0e53a": "padé,ojú, ojú,fi ẹnu ko ẹnu",
"id0870d0": "Ojú tó ń rẹ́rìín músẹ́ pẹ̀lú omijé",
"c54e8e28": "sukún,dunnú,moore,ìwúrí,ọkàn bíbalẹ̀,ẹ̀rín músẹ́",
"fcccdf46": "Ojú aláwàdà",
"a9db0afe": "ojú,bóyín,ya wèrè,dunú,yawọ́",
"c0afa2d6": "Ojú tó ń ṣẹ́jú pẹ̀lú ahọ́n",
"d60ecab0": "ojú,ojú,àwàdà,ahọ́n,ṣẹ́jú",
"j75751da": "Ojú tó fún pọ̀ pẹ̀lú ahọ́n",
"j7917332": "ojú,ojú,èyí tí kò dára,ìtọ́wò,ahọ́n",
"a2145a10": "Ojú pẹ̀lú ahọ́n",
"j962bbbe": "ojú,ahọ́n",
"a156dc52": "Ojú tó ní ẹnu tí owó wà nínú rẹ̀",
"ede0f492": "ojú,owó,ẹnu",
"i47bf280": "Ojú tó nrẹ́rìn músẹ́ pẹ̀lú awò ojú",
"cbeb1882": "mọ́lẹ̀,tutù,ẹyinjú,awò ojú,ojú,àwọn igò ojú,rẹ́rìn músẹ́,oòrùn, awò ojú inú oòrùn,ojú ọjọ́",
"c5e00466": "Ojú ọ̀dẹ̀",
"iefdac4c": "ojú,kò fani mọ́ra,ọ̀dẹ̀",
"bd7f4f78": "Ojú tó farasin",
"e2b36cce": "ìfarasin,awò ojú,ẹni àìmọ̀,imú",
"af0e9da0": "Ojú tó ní awò ojú ẹyọ kan",
"b61e53e0": "móoru,lólá,lówó",
"dee5b628": "Ojú fìlà adamàlúù",
"c02a1a9e": "ọkùnrin tó nṣọ́ màlúù,obìnrin tó nṣọ́ màlúù,ojú,fìlà",
"ac8869b0": "Ojú tó n ṣayẹyẹ",
"ad17a9ac": "ojú,ayẹyẹ,fìlà,fèrè,àríyá",
"g86dbe1e": "Ojú aláwàdà",
"d45be896": "aláwàdà,ojú",
"fd522afe": "Ojú tó nfini ṣe yẹ̀yẹ́",
"d9118d70": "ojú,ojú oníyẹ̀yẹ́",
"a752f0e4": "Ojú tí kò ní ẹnu",
"f8e9f032": "ojú,ẹnu,dákẹ́,panumọ́",
"jc4621ca": "Ojú tó nílà kéékèké",
"he4dd744": "nibańújẹ́,parẹ́,sápamọ́,èèyàn jẹ́ẹ́jẹ́,àìrí",
"f1215032": "Ojú tó kàn wà bẹ́ẹ̀",
"j786bf88": "kò nítumọ̀,ojú,kò fì sí ibi kan",
"e639b180": "Ojú tó ní ẹnú tó wọ́",
"aa3afce4": "já kulẹ̀,kò wúni lórí,siyeméjì,kò dájú",
"cbbfe9d8": "Ojú tó kàn wà ṣá",
"a043cc20": "ojú tó kàn wà bẹ́ẹ̀,ojú,kó sọ̀rọ̀ dáadáa,kò sọ̀rọ̀ dáadáa",
"af66ea50": "Ojú tó kọ́rẹ́ lọ́wọ́",
"b3b5b736": "ojú,kò dunú,àìdunú",
"a6c7d00a": "Ojú tó nyí ẹyin ojú",
"b970b74e": "ojú,ojú,ń yi",
"jebddc86": "Ojú tí irun rẹ̀ sún sókè",
"c39c956c": "àìnígbàgbọ́,oníyèméjì,àìfọwọ́sí,àìgbàgbọ́,ìyanu ìwọ̀nba,oníyèmejì",
"d0e1c490": "Ojú tó nronú",
"ca37204e": "ojú,ń ronú",
"h940fa2a": "Ojú tó gbẹ́nu dákẹ́",
"cdc324e8": "shh,dákẹ́,dákẹ́",
"h4a9c888": "Ojú tó fi ọwọ́ bo ẹnu",
"b9a31402": "ojú,rẹ́rìn músẹ́,bíbò,ẹnu,ọwọ́",
"ef48661c": "Ojú tó síjú sílẹ̀ tó sì fọwọ́ bo ẹnu",
"a2ec38d8": "ohun ìyanilẹ́nu,ìyàlẹ́nu,àìgbàgbọ́,dójútì,bẹ̀rù,ìjọlójú",
"b424f7b6": "Ojú tó ń kíni",
"b3c54252": "ó dá a,ìkínni,oòrùn mú,ikọ̀ ológun,bẹ́ẹ̀ni",
"i85712d2": "Ojú tó nrẹ́rìn músẹ́ tó sì ya ọwọ́ sílẹ̀",
"i736e3f2": "ojú,dìmọ́ra,ń dìmọ́ra",
"gd55409e": "Ojú tóni ojú wíwò",
"h8bce830": "ti mú lọ́kàn,yọjú,ránju,yọjú",
"a09ccb18": "Ojú tó nparọ́",
"cb8a910c": "ojú,irọ́,ti imú",
"c52e5bb4": "Ojú tó nbínú",
"be736e5a": "ìrújú,ojú,ìbínú",
"c406868e": "Ojú ìjákulẹ̀",
"d46030e0": "ìjákulẹ̀,ojú",
"h2df6108": "Ojú tó ní ìdámú",
"fa41bd2e": "ojú,ronú",
"g973f44a": "Ojú tó ní ìrí ìṣẹ́gun",
"e192b22a": "ojú, yege,borí",
"daf1f60a": "Ojú ìbínú",
"c986955a": "ìbínú,ojú,wèrè",
"f09f927e": "Ojú tó nṣu ẹnu pọ̀",
"edfa7bd8": "bínú,ojú,wèrè,ṣu ẹnu síta,bínú gan,pupa",
"ace694b2": "Ojú tó ní àmì lórí ẹnu",
"j6d9aab6": "nṣépè,nbúra,nṣépè",
"f985d6ac": "Ojú tó dààmú",
"e711baee": "kọ̀ sílẹ̀,ojú,ronú gan",
"hfec2c8a": "Ojú tí kò mọ ǹkan tó fẹ́ ṣe",
"a933d28a": "ìrújú,ojú",
"cf8eba8c": "Ojú tó fàro díẹ̀",
"eebf5002": "ojú,fajúro,banújẹ̀,àìdunú",
"b779350e": "Ojú tó fàro",
"dbf08f6e": "Ojú tó rún pọ̀",
"h71e0f26": "ojú,ojú tí kò dára",
"ce66831e": "Ojú ẹlẹ́bẹ̀",
"fcd3e75c": "ojú,bíbẹ̀,àanú,ojú ọmọ ajá",
"h1a4090a": "Ojú tó nmú ǹkan mọ́ra",
"e44518de": "ojú,mú ǹkan mọ́ra",
"j1739d18": "Ojú tó dààmú",
"d50778b8": "dààmú,ojú",
"aa645b44": "Ojú tó rẹ̀",
"cc859cc2": "ojú,ti rẹ̀",
"i553a400": "Ojú àárẹ̀",
"f4171280": "ojú, ti rẹ̀, láarẹ̀",
"hf5f6052": "Ojú tó ń yán",
"f800810e": "ti súni,ti rẹ̀ẹ́,yán",
"g8f3e96c": "Ojú tó nsùn",
"g34862f6": "ojú,sùn",
"h947e02e": "Ojú àárẹ̀",
"f0c21fac": "ojú,mí síta,pọ̀kàkà,ìmí ẹ̀dùn,ìtura,sọ̀rọ̀ kẹ́lẹ́kẹ́lẹ́,súfèé",
"he82ba2c": "Ojú tó lanu sílẹ̀",
"c1a8e600": "ojú,enu,ṣí,ìbákẹ́dùn",
"df3af752": "Ojú tó npariwo pẹ̀lú ẹ̀rù",
"e2d374e2": "ojú,ẹ̀rù,ní ẹ̀rù,jẹ ǹkan lẹ́nu,han",
"fdf40080": "Ojú tó bani lẹ́rù",
"af494ddc": "ojú,ẹ̀rù,ní ẹ̀rù,bẹ̀rù",
"f34b9538": "Ojú tó la ẹnu sílẹ̀ pẹ̀lú ìlàágùn",
"b27d2b12": "búlù,tutù,ojú,ẹnu,ṣi,ṣùrù,làágùn",
"e79df8c8": "Ojú ìjákulẹ̀ ṣùgbọ́n tí ó ní ìtura",
"e3936420": "ìjákulẹ̀,ojú,ìtura,tura",
"f460f02c": "Ojú onílàágùn",
"ca87fef0": "tutù,ojú,ìlàágùn",
"d632657a": "Ojú tó dákẹ́ jẹ́jẹ́",
"d0238cd2": "ojú,dákẹ́,ìyàlẹ́nu,yàlẹ́nu",
"b8f9b6ea": "Ojú tó kórẹ́ lọ́wọ́ tó tún lánu sílẹ̀",
"id5b5394": "ojú,fajúro,ẹnu,ṣí",
"b75da1ee": "Ojú tó wà nínu ìrora",
"bcc4c336": "ìrora,ojú",
"e9479cc6": "Ojú tí kò fẹ́ sunkún",
"f0be1f70": "bínú,sọkún,gbéraga,takò,banújẹ́",
"a00168f6": "Ojú tó nsun ẹkún",
"ha990858": "ẹkún,ojú,banújẹ́,ẹkún",
"fd8d84d0": "Ojú tó nsun ẹkún sókè",
"a085e1c0": "ẹkún,ojú,banujẹ́,sunkún,ẹkún",
"h6b84c24": "Ojú tó ń datọ́ lẹ́nu",
"jd1f091a": "datọ́,ojú",
"c7e6fe6a": "Ó wúni lórí",
"ffd640ea": "ojú,ojú,bóyín,ìràwọ̀,ìtara àìgbọ́n",
"d5c2ae9a": "Ojú tó ní ojú tó dà",
"e438a676": "pòòyì,ojú,wọ́gilé,ojú",
"h5c26840": "Ojú tó ní àwọn ẹyínjú tó ń yí",
"b1c2bf54": "lóòyì ojú,ojú,àwọn ojú,ìrayè,npòyì,wàhálà,ìyàlẹ́nu",
"f1f6c794": "Ojú tó pòyì",
"c7a3fed2": "ojú,kọ̀ òyì,ti mọtí yó,ti mọtí yó díẹ̀,ojú tí kò dọ́gba,ẹnu tón gbọ̀n",
"f4a2fbe8": "Ojú tó ní ìyàlẹ́nu",
"a19a6d5c": "ìyàlẹ́nu",
"fa220726": "Ojú tó ń mì",
"c119301c": "ilẹ̀ ríri,ojú,mì,mì,bẹ̀rù,jáyà,gbọ̀n",
"i87f0152": "Orí tí ó nfọ́nká",
"idd7a184": "ojú,ìyàlẹ́nu,ìbúgbàmù,ya wèrè,nyíni lórí",
"dee3cae6": "Ojú tó ń yọ́",
"cfa3504c": "parẹ́,túká,olómi,yọ́",
"f57b4e4a": "Ojú tí enu ẹ̀ dìpọ̀",
"aa911220": "ojú,ẹnu,ìdi ẹnu pọ̀",
"f2265ada": "Ojú tó ní ìbòjú ìṣègùn",
"fd5564dc": "tutù, dókítà,ojú,ìbojú,oògùn,àárẹ̀",
"gd4458b2": "Ojú tóní ìdiwọ́ àti ìdisẹ̀",
"ja0d3778": "ìdipa di ẹsẹ́,ojú,ìrora, ìpa lára",
"ad28b2de": "Ojú tó ní ẹ̀rọ tí wọ́n fiń wọn ara gbígbóná",
"e2f0d554": "ojú,àìsàn,àárẹ̀,ohun èlò lati mọ ara gbígbóná",
"hdae7ef8": "Ojú tó ń bì",
"cac7842a": "àárẹ̀,èébì,ìlera,èébí",
"jc86ee60": "Ojú tó ń bì",
"f5e5975c": "ojú,àyà rínrin, èébì",
"b10cd120": "Ojú tó ń sín",
"adb5992c": "ojú,àjínde ara,sín",
"bee415ba": "Ojú gbígbóna",
"g328f328": "ojú,ní ibà,ara gbígbóná janjan,gboná, ojú-pípọ́n,ń làágùn",
"i152ef58": "Ojú tútú",
"a2a6a2b0": "ojú,olójú-búlù,òtútù,ó ndi,ìpalara yìnyìn,yìnyín orí òkè",
"i6277392": "Ojú nínú kùrukùru",
"hd9ae9f6": "ojú,àìfiyèsí,àìseéṣeì,àíjòótọ́,àlá,kùrukùru,orí nínú àwọsánmọ̀",
"e9242e0a": "Ojú tó nsùn",
"d82331b8": "ojú, orun,ìhanrun",
"cb83656e": "Àmì orun sísùn",
"e3be0bd6": "àwádà, sùn,ìhanrun",
"be86cf9a": "Ojú tó nrẹ́rin pẹ̀lú àwọn ìwo",
"bd963a4a": "ojú,ìtàn,èrò asán,àwọn ìwo,rẹ́rìn músẹ́",
"c893715a": "Egbére",
"d79e1e04": "ẹ̀mí èṣù,ẹni ibi,ojú,ìtàn ǹkan tó dára,èrò asán,iwinlẹ̀",
"ca34f408": "Ère ilẹ̀ Japan",
"h4e04a06": "ìṣẹ̀dá,ojú,ìtàn,èrò asán,ti ilẹ̀ japan,ẹranko,apanijẹ",
"f5c1af0a": "Iwin ilẹ̀Japan",
"bcfb0878": "ìṣẹ̀dá,ojú,ìtà,èrò asán,ebọra,ti ilẹ̀ japan,ewèlè",
"c70ca6dc": "Àgbájọpọ̀ ìgbẹ́",
"gddeeb08": "ìwé àwàdà,ìgbẹ́,ojú,ewèlé,ìgbẹ́,ìgbẹ́",
"fcf0309c": "Ànjọ̀nnú",
"a2d5d1c8": "ẹ̀dá,ojú,àlọ́,ìrònú-asán,ẹ̀mí,ewèlè,halowíìnì",
"ie1d6550": "Agbárí",
"if4bda4a": "ara,ikú,ojú,àlọ́,ewèlè,eegun agbárí,halowíìnì",
"ed6f0fe2": "Agbárí àti àwọn egungun tí wọ́n gbéléra",
"d9a0e36e": "ara,egungun tí ó kọ́ ara wọn,ikú,ojú,ewèlè,eegun agbárí,halowíìnì",
"cbcd3196": "Ẹ̀mí àjèjì",
"i646283a": "àjèjì,ìṣẹ̀dá,ẹbọra inú igbó,ojú,ìtàn,èrò asán,ewèlè,àlàfo,ẹ̀dá àjèjì",
"i26764dc": "Ojú róbótì",
"e3227376": "ojú,ewèlè,róbótì",
"f2cc36e2": "Èso ìgbà àjọ̀dún",
"cdb4a03e": "iṣẹ́ ṣíṣe,àjọyọ̀,ìdárayá,halowiinì,jaakì,àtùpà,elégédé",
"a6577076": "Ojú olóngbò tó nrẹ́rìn músẹ́ tó lanu sílẹ̀",
"c541d918": "ológbò,ojú,ẹnu,ṣí,rẹ́rìn músẹ́",
"jb2dd692": "Ojú olóngbò tó nbóyín pẹ̀lú ojú tó nrẹ̀rín músẹ́",
"ec4b6534": "ológbò,ojú,bóyín,rẹ́rìn músẹ́",
"f0e4837c": "Ojú ológbò tó ní omijé ayọ̀",
"h6cd103a": "ológbò,ojú,ayọ̀,omijé",
"bdd682f6": "Ojú ológbò tó nrẹ́rin músẹ́ pẹ̀lú ojú tó dàbí ọkàn ",
"c4396450": "ológbò,ojú,ojú,ọkàn,ìfẹ́,rẹ́rìn músẹ́",
"e7c181d6": "Ojú ológbò tó ní ẹ̀rín tó ṣeyẹ̀yẹ́",
"dc53dce8": "olóngbò,ojú,ironic,rẹ́rìn músẹ́,àìdénú",
"caf028b8": "Ojú ológbò tó nfi ẹnu koni lẹ́nù pẹ̀lú ojú pípadé",
"b8cbf192": "ológbò,ojú,ojú,fi ẹnu ko ẹnu",
"c6125382": "Ojú ológbò tó rẹ̀",
"a1b4ea64": "ológbò,ojú,háà,ìyàlẹ́nu,rírẹ̀",
"j66c1262": "Ojú olóngbò tó nsun ẹkún",
"h87b5d5e": "olóngbò,sunkún,ojú,banujẹ́,omijé",
"b07c778c": "Ojú ológbò tó ṣu ẹnu pọ̀",
"e7b8c4c8": "ológbò,ojú,nṣu ẹnu síta",
"hfa461f2": "Àwọn ọwọ́ ọkàn",
"ed51f554": "ìfẹ",
"babbc932": "Ọwọ́ ṣíṣí",
"gd15bfbe": "ara,ọwọ́,ṣí",
"acf7e32e": "Àtẹ́lẹ́ ọwọ́ tó papọ̀",
"baa7f3ac": "ara,àdúra,ọwọ́ tí a ṣù jọ",
"ddc4b578": "Ń káwọ́ sókè",
"d44e2b7c": "ara,àjọyọ̀,fi owó júwè,ọwọ́,ariwo ayọ̀,tí a nà sókè",
"c81aaef2": "Àmí Ìpàtẹ́wọ́",
"hfc5bdba": "ọwọ́ tó npàtẹ́wọ́,ara,pàtẹ́wọ́,ọwọ́",
"e4cc39ba": "Ọwọ́ kíká",
"c4e46c24": "béèrè,ara,tẹríba,kápọ̀,ìfọwọ́júwè,ọwọ́,jọ̀wọ́,gbàdúrà,oṣeun",
"ae3d36c6": "Ìbọwọ́",
"ia2d4486": "àdéhùn,ọwọ́,ìbọwọ́,ìpàdé,bọwọ́",
"b066e85a": "Ó bójú mu",
"a467b0e8": "ara,òké,ọwọ́,ọmọ ìka ńlá,àwọn ọmọ ìka ńlá lókè,+1",
"ada4be42": "àmì àìbójúmu",
"b0384782": "ara,ìsàlẹ̀,owọ́,ọmọ ìka ńlá,ọmọ ìka ńlá wálẹ̀,-1",
"hbd90a8c": "Ọwọ́ tó ṣupọ̀",
"b6036146": "ara,ṣupọ̀,ìkúùkù,ọwọ́,ẹ̀ṣẹ̀,ń bọ̀",
"ja53ada6": "Ẹ̀ṣẹ́ tí a gbé sókè",
"b3f8f378": "ara,ṣùpọ̀,ẹ̀ṣẹ́,ọwọ́,ju ẹ̀ṣẹ́",
"fd2b9c1c": "Ẹ̀ṣẹ́ tó kọjú sí apá òsì",
"a05f8b0c": "ará,ìkúùkù,sí apá òsì",
"d8ef2b9a": "Ẹ̀ṣẹ́ tó kọjú sí apá ọ̀tún",
"d0c3803c": "ará,ìkúùkù,sí apá ọ̀tún",
"d9f47c0a": "Ìka tó kọ́ ra wọn",
"c47d97e4": "ara,àgbélébú,ìka,ọwọ́,oríre",
"f631ab6a": "Ọwọ́ Ìṣẹ́gun",
"a3a1cf88": "ara,ọwọ́,v,ìṣẹ́gun",
"ieb62a2a": "Ọwọ́ tó ní ọwọ́ ààrin àti àtàǹpákò tó kọ́ ara wọn",
"c50beb34": "wọ́n,ọkàn,ìfẹ́,owó,rẹjú",
"c8bd1586": "Àmì ìwo",
"ebf78b94": "ara,ìka ọwọ́,ọwọ́,àwọn ìwo,àríyá",
"a4d65da2": "Ìfọwọ́júwé mo ní ìfẹ́ rẹ",
"g728105c": "ara,mo ní ìfẹ́ rẹ,mo ní ìfẹ́ rẹ,ọwọ́",
"fc084206": "Ọwọ́ ó dáa",
"a1b9c674": "ara,ọwọ́,ó dára",
"he3b496c": "Ìka tí a já léèkáná",
"f02beee4": "àwọn ìka,ìfarajúwe ọwọ́,ìbéèrè,já léèkáná,ìpẹ̀gàn",
"de8feb1c": "Ọwọ́ tó n jáni lèékánná",
"ed90b008": "ara,ọwọ́,kéré,tíntiní,wíníwíní",
"f4709a30": "Ẹyin ọwọ́ ìka kékeré tó nnawọ́ sí apá òsì",
"b9aac656": "ẹ̀yìn ọwọ́,ara,ìka ọwọ́,ọwọ́,ìka tó kẹ́yìn ọwọ́,nàka",
"a97f2e70": "Ọwọ́ tí àtẹ́lẹwọ́ dojúdé",
"ce4a8abe": "túká,jùúlẹ̀,máa lọ",
"afe692c0": "Ọwọ́ tí àtẹ́lẹwọ́ sí sóké",
"b0bb595a": "ṣẹ́wọ́ sí,mú,wá,ìfilọ̀",
"ee762494": "Ẹyin ọwọ́ ìka kékeré tó nnawọ́ sí apá ọ̀tún",
"cb636654": "Ẹyin ọwọ́ ìka kékeré tó nawọ́ sí òkè",
"ce4ecf82": "ẹ̀yìn ọwọ́,ara,ìka ọwọ́,ọwọ́,ìka ọwọ́ tó kẹ́yìn,nàka,sókè",
"j2706b2c": "Ẹyin ọwọ́ ìka kékeré tó nawọ́ sísàlẹ̀",
"e943dc48": "ẹ̀yìn ọwọ́,ara,ìsàlẹ̀,ìka ọwọ́,ọwọ́,ìka tó kẹ́yìn ọwọ́,nàka",
"ee1acfdc": "Ìka kékeré tó nawọ́ sókè",
"h2929fb6": "ara,ìka ọwọ́,ọwọ́,ìka ọwọ́ tó kéhìn,nàka,sókè",
"ade08cd8": "Ọwọ́ nínà sókè",
"a7a48a9c": "ara,ọwọ́",
"c84b74e0": "Ẹ̀yìn ọwọ́ tí a nà sókè",
"cbc5bed6": "ara,ẹ̀yìn ọwọ́,ti gbé e sókè",
"ce77ef82": "Nawọ̀ pẹ̀lú ìka tó pínyà",
"eab350d8": "ara,ìka ọwọ́,ọwọ́,tó pínyà",
"g86423a2": "Ọwọ́ tó ná sókè tóní àlàfo láàrín àti ìka òrùka",
"eb5c226c": "ara,ìka ọwọ́,ọwọ́,spọ́ọ̀kì,vulcan",
"a91f870e": "Ọwọ́ tí à ń jù",
"j8ed1936": "ara,apá,juwọ́,ń juwọ́,ǹlẹ́ ǹlẹ́",
"g2ee54d8": "Ọwọ́ pè mí",
"i247d02c": "ara,ìpè,ọwọ́",
"dccdecd6": "Ọwọ́ apá òsì",
"adad418a": "ọwọ́,òsì,apá òsì",
"a6f5166c": "Ọwọ́ apá ọ̀tú",
"a454a1e6": "ọwọ́,ọ̀tún,apá ọ̀tún",
"eb4f0050": "Ọwọ́ apá òsì tó ń ṣiṣẹ́",
"dc697742": "kọ̀,ga,márùn-ún,ti,apá òsì,tì,kọ̀,dádúró,dúró",
"f1f7fa90": "Ọwọ́ apá ọ̀tún tó ń ṣiṣẹ́",
"b5b62194": "kọ̀,ga,márùn-ún,ti,apá òsì,tì,kọ̀,dádúró,dúró",
"e146e4dc": "Iṣan apá tí a ràn",
"e1541276": "iṣan apá,ara,ìwé àwàdà,nara,iṣan",
"cdf18830": "Apá ẹlẹ́rọ",
"a52a4ace": "ìráàyèsí,ẹ̀yà ara àtọwọ́dá,ara",
"g92f89d4": "Òdìkejì ọwọ́ àárín tó nà",
"e4941f98": "ara,ìka ọwọ́,ọwọ́,ìka ọwọ́ àárín",
"fa36172a": "Ọwọ́ ààrin ń nàka sí olùwòran",
"db65f38e": "tọ́ka,ìwọ,ìka",
"j99675dc": "Ọwọ́ ìkọ̀wé",
"aba9accc": "ara,ọwọ́,kọ̀wé",
"b80d4590": "Àwòrán ara ẹni",
"hac34174": "kámẹ́rà,fóònù,àwòrán ayàfúnraẹni,apá",
"fd41ead6": "Ọdà èékánná",
"ha73fc54": "ara,ìtọ́jú,èròjà aṣaralóge,ìtọ́jú ọwọ́,èékáná,ọ̀dà ìka ọwọ́",
"ebd6cc2e": "Ẹsẹ̀",
"cd5b3924": "ara,fẹsẹ̀gbá,ẹsẹ̀ tàbí apá",
"c2753a32": "Ẹsẹ̀ ẹlẹ́rọ",
"aec21cea": "Àtẹlẹsẹ̀",
"j120b20e": "ara,fẹ̀sẹ̀gbá,jansẹ̀mọ́lẹ̀",
"cd215e00": "Ẹnu",
"fd05205c": "ara,ètè,ẹnu",
"db01fda6": "Ngé ètè jẹ",
"de291856": "ṣe àníyàn,ìbẹ̀rù,ìtage,ìbẹ̀rùbojo,ìfòyà,kọminú",
"bf8894ee": "Eyín",
"d68f746e": "ara,eyín,dókítà ìtọ̀jú ẹyín",
"e9055042": "Ahọ́n",
"bec854e2": "ara,ahọ́n",
"aea69064": "Etí",
"cbefa16a": "ara,imú",
"fc9f62ac": "Ètí pẹ̀lú ohun èlò ìgbọ́ròó ",
"fdf2b368": "ìráàyèsí,gbígbọ́,ara,etí",
"ee07a378": "Imú",
"e0b955aa": "Ojú",
"hbc7a7d2": "ara,ojú",
"ha8b1fa2": "Ojú",
"j8fc4c64": "ara,ojú,ojú",
"a46c86c4": "Ọpọlọ",
"ed060ae8": "ara,ẹ̀yà inú ara,ọlọ́gbọ́n,ọlọ́gbọ́n",
"fa118a7e": "Ọkàn àfojúrí",
"c572e2a2": "ẹ̀kọ́ nípa ẹ̀ya-ara, ìmọ̀ nípa ọkàn,ọkàn,ẹ̀ya ara,ìlùkìkì ọkàn",
"jac35d00": "Ẹ̀dòfóró",
"d9b0e40a": "èémí,mímí jáde,mímí sínú,ẹ̀dọ̀fóró,ẹ̀ya ara, mímí",
"c0044324": "Eegun",
"f11ced26": "ara,egungun",
"c57ec7cc": "Ère ènìyàn dúdú",
"e098f544": "bust,àwòrán",
"d1d776a2": "Àwọn ère ènìyàn dúdú",
"e3954154": "Orí tó n sọ̀rọ̀ nínu iná dúdú",
"d898fda4": "ojú,orí,àwòrán,sọ̀rọ̀,ń sọ̀rọ̀",
"afc9d6b2": "Àwọn èyàn tó ń dì mọ́ ara wọn",
"i1a2fb14": "ó dáàbò,ǹlẹ́,dídiramú,ìdúpẹ́",
"ef89bbf6": "Ọmọ Ìkókó",
"a0f4baac": "ọmọ ìkókó",
"ec2007f2": "Ọmọbìrin",
"e6d5fcbc": "ọmọdébìnrin,obínrin àgbálagbà,wúndíá,àmì wúndíá,àkọsẹ̀jayé,ọmọdé",
"ie9ec9aa": "Ọmọdé",
"ab64ed06": "ènìyàn,ọmọdé,ọmọdékùnrin,ọmọdébìnrin",
"aee1246e": "Ọmọdékùnrin",
"e1b22ae6": "ọmọdékùnrin,ọmọdé",
"b00fb4e4": "Obìnrin",
"e4bc8472": "obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"da7d16ec": "Àgbàlagba",
"bba738f8": "ènìyàn,àgbàlagbà,ọkùnrin,obìnrin,akọ,abo,àwọn ọkùnrin,àwọn obìnrin",
"dca20e16": "Ọkùnrin",
"e9d02bd6": "ọkùnrin,irùnmú,akọ,àwọn ọkùnrin",
"a8a613ca": "obìrin,onírun tó ṣupọ̀",
"ddd1ca7a": "ṣùpọ̀,irun,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"f315fd58": "èyàn, onírun tó ṣupọ̀",
"ee212486": "ṣupọ̀,irun",
"h8e0b104": "Ọkùnrin,onírun tó ṣupọ̀",
"fb44ad3e": "ṣùpọ̀,irun,ọkùnrin,abo,àwọn ọkùnrin",
"a9e761f4": "Obìrin,onírun pupa",
"j0eaf784": "pupa,irun,obìrin,abo,àwọn obírin",
"c18d26a6": "èyàn,onírun pupa",
"jcc45a72": "pupa,irun",
"g5eaa788": "Ọkùnrin, onírun pupa",
"gbbb10d2": "pupa,irun,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"ba986aa8": "Obìrin,onírun àwọ̀ òféfèé",
"a2ed441c": "irun tó ṣá,irun tó ṣá,irun,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"j0f5490e": "Èyàn,onírun àwọ̀ òféfèé",
"efa46aaa": "àwọ̀ òféfèé,àwọ̀ òféfèé,irun",
"adb881ac": "Ọkùnrin, onírun àwọ̀ òféfèé",
"ge31adb8": "irun tó ṣá,irun tó ṣá,irun,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"a1da0d54": "Obìnrin,onírun funfun",
"j4e12298": "funfun,irun,obìrin,abo,àwọn obìrin",
"d31d1f94": "Èyàn, onírun funfuun",
"a42c4166": "funfun,irun",
"de816438": "Ọkùnrin, onírun funfun",
"e3df85b2": "funfun,irun,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"a76da292": "Obìrin, párí",
"j62e7d58": "párí,obìrin,abo,àwọn obìrin",
"a5214fa4": "Èyàn,párí",
"d6ba18b4": "párí",
"fa55eb7c": "Ọkùnrin, párí",
"g1ea9ef0": "párí,akọ,abo,àwọn ọkùnrin",
"ab10657e": "Obìnrin onírungbọ̀n",
"d6cb3888": "irugbọ̀n,ní irun limú,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"j5606bb8": "Ẹni tó ní iru àgbọ̀n",
"a29c98f8": "irùngbọ̀n,onírùn imú",
"b7bee224": "Ọkùnrin onírugbọ̀n",
"bb14a38a": "irùngbọ̀n,ní irun imú,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"c5e50d58": "Obìnrin àgbàlagbà",
"b6500cc4": "àrúgbó,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"gf84f310": "Àgbálagbà",
"b64e6ba4": "ènìyàn,arúgbó,ọkùnrin,obìnrin,akọ,abo,àwọn ọkùnrin,àwọn obìnrin",
"bcd7dd7a": "Ọkùnrin àgbàlagbà",
"b3c15ba6": "arúgbó,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"fedbf480": "Èyàn tó wọ fìlà agbárí",
"c0ca692c": "fìlà ilẹ̀ China,fìlà",
"i803e818": "Obìrin tó wọ láwàní",
"fed6d7e0": "ìbòrí,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"i883cebc": "Èyàn tó wọ láwàní",
"adcfa678": "láwàní",
"f0224378": "Ọkùnrin tó wọ láwàní",
"c7121a9a": "ìbòrí,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"aff6a868": "Obìnrin tó ní ìborùn",
"dfe39650": "ìborùn,hijaabù,ìborùn,ìborùn,ìborùn,ìborùn,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"cbf35a90": "Ọlọ́pàá obìrin",
"j7b18c58": "ọlọ́pàá,òṣìṣẹ́,ọlọ́pàá,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"f62d972e": "Ọlọ́pàá",
"ec1c0b92": "ọlọ́pàá,òṣìṣẹ́,ọlọ́pàá",
"i1c56884": "Ọlọ́pàá ọkùnrin",
"j2f0908c": "olọ́pàá,òṣìṣẹ́,ọlọ́pàá,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"e27a7430": "Panápaná obìrin ",
"d1a330aa": "iná,panápaná,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"a64deb70": "Panápaná",
"f01b0148": "iná,panápaná",
"gfa4e340": "Panápaná Ọkùnrin ",
"c0634138": "iná,panápaná,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"ebb3f6c2": "Òṣìṣẹ́ ilé-kíkọ́ obìrin",
"i0372442": "ìkólé,òṣìṣẹ́,obìnrin,,abo,àwọn obìnrin",
"a398fba0": "Òṣìṣẹ́ tó nkọ́ ilé",
"ea898d80": "ìkọ́lé,òṣìṣẹ́",
"f55fbe1e": "Òṣìṣẹ́ ilé-kíkọ́ ọkùnrin",
"i6bdbd5c": "ilé-kíkọ́,òṣìṣẹ́,ọkùnrin,abo,àwọn ọkùnrin",
"b525e73a": "Òṣìṣẹ́ ilé-iṣẹ́-ẹ̀rọ obìrin",
"e47ae3f0": "ilé iṣẹ́ ńlá,ti ilé iṣẹ́,welder,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"c33dfdd0": "Òṣìṣẹ́ ilé-iṣẹ́-ẹ̀rọ",
"db68f71c": "ilé-iṣẹ́-ẹ̀rọ,jọ mọ́ ilé-iṣẹ́-ẹ̀rọ,jórin-jórin",
"b47eef7e": "Òṣìṣẹ́ ilé-iṣẹ́-ẹ̀rọ ọkùnrin ",
"f078b330": "ilé iṣẹ́ ńlá,ilé iṣẹ́,ajórin,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"e511fbdc": "Mọ́kálíìkì obìrin",
"a01fbf18": "olùtajà,oníṣẹ́ ẹ̀rọ omi,oníṣẹ́ mànàmáná,atún-nǹkan-ṣe,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"bd714946": "Mọ́kálíìkì",
"ec31e010": "olùtajà,oníṣẹ́ ẹ̀rọ omi,oníṣẹ́ mànàmáná,atún-nǹkan-ṣe",
"b6d1dac2": "Mọ́kálíìkì ọkùnrin",
"bfb1cc36": "olùtajà,oníṣẹ́ ẹ̀rọ omi,oníṣẹ́ mànàmáná, atún-nǹkan-ṣe,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"d6196d6e": "Àgbẹ̀ obìrin",
"i411225c": "òṣìṣẹ́ oko,alágbo-ẹran,olùṣọ́gbà,iṣẹ́ oko,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"g7e01b2a": "Àgbẹ̀",
"c7564312": "òṣìṣẹ́ oko,alágbo-ẹran,olùṣọ́gbà,oko ṣíṣe",
"i4abadd4": "Àgbẹ̀ ọkùnrin",
"f8f049f6": "òṣìṣẹ́ oko,alágbo-ẹran,olùṣọ́gbà,iṣẹ́ oko,okùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"d1506df8": "Alásè obìrin",
"f6dd58ec": "óúnjẹ,ìpèsè,olùṣè,olópò,ń se óúnjẹ,abo,àwọn obìnrin",
"c78eadfc": "Dáná",
"de5dbe22": "oúnjẹ,iṣẹ́,alásè,agbọ́únjẹ,dáná,iná dídiá",
"ad201b46": "Alásè ọkùnrin",
"cf252fa4": "óúnjẹ,ìpèsè,olùsè,olópò,ń se óúnjẹ,okùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"d25db246": "Akọrin obìrin",
"a475170e": "orin,olórin,olórin,ìlúmọ̀ọ́ká olórin,adánilárayá,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"a9c63c0c": "Akọrin",
"b313da32": "orin,olórin,olórin ìgbàlódé,olórin gbajúmo,adánilárayá",
"be66cf0c": "Akọrin ọkùnrin",
"f1e710de": "orin,olórin,olórin,ìlúmọ̀ọ́ká olórin,adánilárayá,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"b88a0b80": "Oníṣẹ́-ọnà obìrin",
"d37863b2": "iṣẹ́ ọnà,olórin,ọ̀dà,a kun ọ̀dà,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"ff4b6714": "Oníṣẹ́-ọnà",
"aea72b14": "ọnà,oníṣẹ́-ọnà,kùn,akunlé",
"f5cab50a": "Oníṣẹ́-ọnà ọkùnrin",
"bad011ac": "iṣẹ́ ọnà,olórin,ọ̀dà,a kun ọ̀dà,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"b87a92d0": "Olùkọ́ obìrin",
"b47b8746": "ẹ̀kọ́,olùkọ́,ọmọ̀wé,olùkọ́ni,olùtọ́nisọ́nà,abo,àwọn obìnrin",
"a3a40ee2": "Olùkọ́",
"h7e48274": "ẹ̀kọ́,olùkọ́,ọ̀jọ̀gbọ́n,akọ́ni,ọlùtọ́sọ́nà",
"bd809f3a": "Olùkọ́ ọkùnrin",
"a35d1712": "ẹ̀kọ́,olùkọ́,ọmọ̀wé,olùkọ́ni,olùtọ́nisọ̀nà,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"d4b29090": "Akẹ́kọ̀ọ́ obìrin",
"fa402c26": "akẹ́kọ̀ọ́,akọ́kọ̀ọ́gboyè,ẹ̀kọ́,ilé ìwé,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"e6c08854": "Akẹ́kọ̀ọ́",
"d49200fc": "akẹ́kọ̀ọ́,kẹ́kọ̀ọ́ gboyè,ẹ̀kọ́,ilé-ìwé",
"j00c118a": "Akẹ́kọ̀ọ́ ọkùnrin",
"e9590fb4": "akẹ́kọ̀ọ́,akẹ́kọ̀ọ́gboyè,ẹ̀kọ́,ilé ìwé,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"e3465dbe": "Òṣìṣẹ́ ilé-iṣẹ́ obìrin",
"ja90ffdc": "ibiṣẹ́,aṣírò owó,òṣìṣẹ́ ilé ìfowópamọ́,alákóṣo,olùdámọ̀ràn,akọ̀wé,amòye,obìnrin ,abo,àwọn obìnrin",
"aa94556a": "Òṣìṣẹ́ ọfíìsì",
"adafa002": "ilé-iṣẹ́, aṣírò owó,òṣìṣẹ́ bankì,olùṣàkóso,olùdámọ̀ràn,akọ̀wé,oníwàádì",
"b8ab46d8": "Òṣìṣẹ́ ilé-iṣẹ́ ọkùnrin",
"i240c5cc": "ibiṣẹ́,aṣírò owó,òṣìṣẹ́ ilé ìfowópamọ́,alákoso,olùdámọ̀ràn,akọ̀wé,amòye, ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"f99f86ea": "Onímọ̀ tẹkinọ́lọ́jì obìrin",
"i6c31f6e": "ìmọ̀ ẹ̀rọ,àìrídimú,onímọ̀ ẹ̀rọ,oníkoodù,kòmpútà àgbélétan,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"d8a32d52": "Onímọ̀ tẹkinọ́lọ́jì",
"h454424a": "tẹkinọ́lọ́jì,softwià,ẹnjiníà,onímò kóòdù,kọ́mpútà àgbéká",
"f32f5a00": "Onímọ̀ tẹkinọ́lọ́jì ọkùnrin",
"e56629b6": "ìmọ̀ ẹ̀rọ,àìrídìmú,onímọ̀ ẹ̀rọ,oníkoodù,kòmpútà àgbélétan,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"h9c2b5e4": "Onímọ̀ sáyẹ́nsì obìrin",
"d41810f2": "onímọ̀ sáyẹ́nsì, kẹ́mísítì, onímọ̀ ẹ̀rọ,onímọ̀ ìṣirò,onímọ̀ físíksì,onímọ̀ ẹ̀dá àyè, onímọ̀ iṣẹ́ láàbù,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"c4c64e52": "Onímọ̀ sáyẹ́nsì",
"c33abee4": "onímọ sáyẹ́nsì,kẹ́mísítì,ẹnjiníaà,onímọ̀ ìṣirò,onímọ̀ físíksì,onímọ̀ ẹ̀dá àyè,onímọ̀ iṣẹ́ láàbù",
"f3297d7c": "Onímọ̀ sáyẹ́nsì ọkùnrin",
"b17ff1e4": "onímọ̀ sáyẹ́nsì,kẹ́mísítì,onímọ̀ ẹ̀rọ,onímọ̀ ìṣirò,onímọ̀ físíksì,onímọ̀ ẹ̀dá àyè, onímọ̀ iṣẹ́ láàbù,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"d987b942": "Ástírónọ́ọ̀tì obìrin",
"f6022954": "àayè,àwọn ìràwọ̀,òṣùpá,àwọn ẹ̀dá ojú ọ̀run,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"a3180598": "Ástírónọ́ọ̀tì",
"jfd309da": "àyè,ìràwọ̀,òṣùpá,àwọn pílánẹ́ẹ̀tì",
"ge12ba78": "Ástírónọ́ọ̀tì Ọkùnrin",
"cb875986": "ààyè,àwọn ìràwọ̀,òṣùpá,àwọn ẹ̀dá ojú ọ̀run,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"g3578400": "Òṣìṣẹ́ ìlera obìrin",
"d7133242": "dókítà,oníṣègùn,dokità àgbà,nọ́ọ̀sì, dókítà eyín,olùtọ́jú ìlera,akọ́ṣẹ́mọṣẹ́, olùtọ́jú,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"i39c245c": "Òṣìṣẹ́ ìlera",
"be6619b4": "dókítà, oníṣègùn,àgbà dókítà,nọ́ọ̀sì,dókítà eyín,onítọ́jú ìlera,olùtọ́jú",
"d99275d4": "Òṣìṣẹ́ ìlera ọkùnrin",
"c8ff1d50": "dókítà,oníṣègùn,dokità àgbà,nọ́ọ̀sì, dókítà eyín,olùtọ́jú ìlera,akọ́ṣẹ́mọṣẹ́, olùtọ́jú,okùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"e9a7160a": "Adájọ́ obìrin",
"c0bbe176": "adájọ́,ilé ẹjọ́,òfin,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"ec3819c2": "Adájọ́",
"a3620108": "adájọ́,ilé-ẹjọ́,òfin",
"d523dc0e": "Adájọ́ ọkùnrin",
"ga115584": "adájọ́,ilé ẹ̀jọ́,òfin,ọkùnrin,akọ,àwọn obìnrin",
"d8b443de": "Awakọ̀ òfurufú obìrin",
"jca578fe": "awakọ̀ ọkọ̀ òfurufú,ọkọ̀ òfurufú,awakọ̀ ọkọ̀ òfurufú,awakọ̀ ọkọ̀ òfurufú, obìnrin, abo,àwọn obìnrin",
"c27aacb0": "Awakọ̀ òfurufú",
"f4d3f290": "awakọ̀ òfurufú,ọkọ̀ òfurufú,awakọ̀ òfurufú,wíwa ọkọ̀ òfurufú, ",
"c85f3ed6": "Awakọ̀ òfuurufú ọkùnrin",
"a12e2556": "awakọ̀ ọkọ̀ òfurufú,ọkọ̀ òfurufú,awakọ̀ ọkọ̀ òfurufú,awakọ̀ ọkọ̀ òfurufú, ọkùnrin, akọ,àwọn ọkùnrin",
"da4b004e": "Ẹ̀ṣọ́ obìrin",
"d865ae6e": "olùṣọ́,olùṣọ́ ọkùnrin,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"g56351d4": "Ẹ̀ṣọ́",
"fbadfeee": "ẹ̀ṣọ́,ẹ́ṣọ́ ọkùnrin",
"fdb9f3d6": "Ẹ̀ṣọ́ ọkùnrin",
"d6d20d3e": "olùṣọ́,olùṣọ́ ọkùnrin,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"j67fd6c8": "Ninja",
"jbfd16b0": "jagunjagun,ní ìpamọ́,ninja,ìyọ́kẹ́lẹ́",
"ba8724da": "Ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ obìrin",
"aa3e1846": "ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́,olùwádìí,amí,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"b7eb8c30": "Ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́",
"c75d90c4": "ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́,oníwàádì,amí",
"ce9eb8fa": "Ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ ọkùnrin",
"jae0b68e": "ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́,olùwádìí,amí,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"d8e92b9a": "Ìyáàfin Claus",
"d608fecc": "iṣẹ́ ṣíṣe,àjọyọ̀,kérésìmesì,ìyá,mama kérésìmesì,baba,keresì,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"ca7f6e7c": "Mx Claus",
"fb940aa0": "ìṣe,ayẹyẹ,kérésìmesì,bàba kérésì,bàba kérésì",
"h5513cee": "Bàbá Kérésì",
"bf8f261a": "iṣẹ́ ṣíṣe,àjọyọ̀,kérésìmesì,bàbá,baba,kérésìmsì,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"d1b6ced6": "Àngẹ́lì ọmọdé",
"b1e87a0e": "áńgẹ́lì,ọmọ ìkókó,ojú,ìtàn,ìròkurò",
"bd3f04f6": "Ojú ológbò tó ní ẹ̀rín tó ṣeyẹ̀yẹ́",
"he2a9690": "ìtàn tó dára,ìròkurò,ọmọba obìnrin,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"gf91ae68": "Èèyàn pẹ̀lú adé",
"c928f7c0": "Ìtàn àròsọ,rònú asán,orí adé,ọlọ́lá,ti ọba,ọlọ́ba",
"he9d67fe": "Ọmọ ọba ọkùnrin",
"i9e681ec": "ìtàn tó dára,ìròkurò,ọmọba ọkùnrin,ọkùnrin,akọ,àwọn okùnrin",
"ifd222fa": "Obìrin tó wé ìbòjú",
"ga428a90": "ìyàwó,ìbòrí,ìgbeyàwó,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"a016789c": "Èyàn tó wọ ìbojú",
"j93a5f1c": "ìyàwó,ìbojú,ìgbéyàwó",
"i3855b50": "Ọkùnrin tó wé ìbòjú",
"f65736c6": "ìyàwó,ìbojú,ìgbéyàwó,ọkùnrin,abo,àwọn ọkùnrin",
"ef4e9d9a": "Ọbìnrin tó wọ aṣọ àpèjẹ",
"a31db51e": "aṣọ àpèjẹ,ìgbéyàwó,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"jdcd1110": "èyàn to wọ tuksẹdò",
"e0768c28": "ọkọ ìyàwọ́,tuksẹdò,ìgbéyàwó",
"dc4b0f7e": "Ọkùnrin tó wọ tuksedo",
"b7d36534": "ọkọ ìyàwó,aṣọ àpèjẹ,ìgbéyàwó,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"j8a1e220": "Ọkàn àwọ̀ píìkì",
"c733a644": "rẹwà,ọkàn,fẹ́ràn,ìfẹ́,píǹkì",
"i5bdf070": "Ọkàn àwọ̀ omi aró fẹ́ẹ́rẹ́fẹ́",
"b32a19c0": "cyan,ọkàn,àwọ aró fẹ́ẹ́rẹ́fẹ́,teal",
"e316fa8e": "Ọkàn àwọ̀ eérú",
"ca44ede8": "àwọ̀ eérú,ọkàn,àwọ̀ fàdákà,síléètì",
"f03b3ff0": "Obìnrin tó wọ aṣọ àwọ̀ṣiṣẹ́ tó ń rábàbà",
"g8c78e02": "òwò,ẹ̀wù,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"b54533ba": "Èyàn tó wọ aṣọ àwọ̀ṣiṣẹ́ tó ń rábàbà",
"ff0c512e": "òwò,aṣọ ẹ̀wù",
"ba650b52": "Ọkùnrin tó wọ aṣọ àwọ̀ṣiṣẹ́ tó ń rábàbà",
"je3858ac": "òwò,ẹ̀wù,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"abdf111e": "Arábìnrin akọni",
"eedc4730": "ìrònú-asán,rere,akọni,awọn agbara ògbóǹtarìgì,obìrin,akọ,àwọn obìrin",
"c4abb940": "Àràmàǹdà ẹ̀dá",
"ge9a3ee2": "ìrònú-asán,dára,akọni, akọni obìnrin,àwọn orílẹ̀-èdè alágbára ńlá",
"i8d54d82": "Àràmàǹdà ẹ̀dá ọkùnrin",
"d3ff4442": "ìrònú-asán,rere,akọni,awọn agbara ògbóǹtarìgì,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"ee184498": "Èèyànkéèyàn ńlá obìrin",
"bd60a8ca": "ìrònú-asán,burúkú,ọ̀dáràn,burú,awọn alagbara ògbóǹtarìgì,èèyànkéèyàn, obìrin,abo,àwọn obìrin",
"d039b8fe": "Èèyànkéèyàn ńlá",
"c825b376": "ìrònú-asán,burúkú,ọ̀daràn,bìlísì,àwọn orílẹ̀-èdè alágbára ńlá,èyàn búburú",
"jc27a4ae": "Èèyànkéèyàn ńlá ọkùnrin",
"d50237c0": "ìrònú-asán,burúkú,ọ̀dáràn,burú,awọn alagbara ògbóǹtarìgì,èèyànkéèyàn, ọkùnrin,akọ,àwọn arákùnrin",
"ac276008": "Obìnrin onídán",
"e42588fc": "ìròkírò,àjẹ́,àjẹ́,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"eee1f142": "Onídán",
"dd83a4aa": "ìrònú-asán, oṣó, oṣó",
"e067996c": "Ọkùnrin onídán",
"c08c59b0": "ìròkírò,oṣó,oṣó,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"fe2dbdbc": "Obìnrin iwin",
"f9cb81ae": "ìròkírò, iwin, etí gbọọrọ,obìnrin,abo,àwọn ọbìnrin,",
"c7baa96c": "Iwin",
"a07586ec": "ìrònú-asán,iwin,etí gbọọrọ",
"dd5314fe": "Ọkùnrin iwin",
"jbd6dc3c": "ìròkírò, iwin, etí gbọọrọ,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"dbed65b2": "Ọbìnrin ànjọ̀nnú",
"fc313c8e": "ìròkírò,ayaba àwọn iwin,ìyẹ́,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"j5eb5024": "Ànjọ̀nnú",
"j4fe4ede": "ìrònú asán,titania,ìyẹ̀ apá",
"gbd7d066": "Ọkùnrin ànjọ̀nnú",
"b76773a4": "ìròkírò,ọba àwọn iwin,pọọkì,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"j9990ae4": "Obìnrin genie",
"d995eb3a": "ìròkírò,àjọ̀nnú,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"d4009638": "Iwinlẹ̀",
"d3b2b864": "ìrònú-asán,jínì",
"hd7c2812": "Ọkùnrin genie",
"d1c19c70": "ìròkírò,àjọ̀nnú,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"gb3d6f52": "Ọmọbìnrin omi",
"d44f2cb8": "ìròkírò,olúwẹri,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"c0fbacd0": "Yemọja",
"e3c6cebe": "ìrònú asán,ọmọbìnrin omi",
"c902786a": "Ọmọkùnrin omi",
"i9e7e526": "ìrònú-asán,ọmọbìnrin omi,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"j698f70e": "Òburẹ́wà",
"b74f2ed2": "ìtàn àròsọ,ìrònú asán,ewèlè",
"b481ef36": "Obìnrin jòkújòkú",
"eb59c18c": "ìròkírò,unded,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"e32ce22a": "Jòkújòkú",
"d6d1fc4c": "ìrònú asán,drakúlà,àìkú",
"ia8896be": "Ọkùnrin jòkújòkú",
"a614ee40": "ìròkírò,drakulà,àìkú,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"fc51661e": "Òkúbìnrin tí a pè",
"he1d1ec2": "ìròkírò,àìkú,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"d5be55d8": "Òkú tí a pè",
"e04d8638": "ìrònú asán,àìkú",
"bbc7c52a": "Òkúkùnrin tí a pè",
"g0472f72": "ìròkírò,àìkú,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"i096722a": "Obìnrin tó ntẹríba gan",
"e5ff19fc": "ẹ̀bẹ̀,tẹríba,ìfọwọ́júwé,mábínú,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"ac020db2": "Ènìyàn tó ntẹríba gìdánimọ̀i",
"ef5d117a": "ẹ̀bẹ̀,tẹríba,ìfarajúwe,má binú",
"eef25fb8": "Ọkùnrin tó ntẹríba gan",
"bed1651e": "ẹ̀bẹ̀,tẹríba,ìfowọ́júwé,mábínú,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"j2084638": "Ọwọ́ obìnrin tó nfun ni ní ẹ̀gúnjẹ",
"a9f443ba": "ọwọ́,ìrànwọ̀,àlàyé,ní ìlera,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"e1c556aa": "Èyàn to fi ọwọ́ ẹ̀ hàn",
"df5bb59e": "Ọwọ́ ọkùnrin tó nfun ni ní ẹ̀gúnjẹ",
"a28102ac": "ọwọ́,ìrànwọ́,àlàyé,ní ìlera,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"bbffabfa": "Obìnrin tó n sàmì pé kò dáa",
"a0055284": "èwọ̀,ìfọwọ́júwé,ọwọ́,bẹ́ẹ̀kọ́,rárá,èwọ̀,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"ia102a4c": "Èyàn tó n sàmì pé kò dáa",
"h7190638": "èwọ̀,ífrajúwe,ọwọ́,rárá,kìí,ti kọ̀",
"a3eefc26": "Ọkùnrin tó n sàmì pé kò dáa",
"d52dc816": "èwọ̀,ìfọwọ́júwé,ọwọ́,bẹ́ẹ̀kọ́,rárá,èwọ̀,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin,",
"cf6f6d96": "Obìnrin tó n sàmì pé ò dáa",
"c4bfb8f6": "ìfọwọ́júwé,ọwọ́,ó dára,obìnrin,abo,àwọn obìnrin,",
"c7b4f910": "Èyàn tó n sàmì pé ó dáa",
"a4e6a8f4": "ìfarajúwe,ọwọ́,ó dáa",
"e685fb1c": "Ọkùnrin tó n sàmì pé ò dáa",
"ib5fc638": "ìfọwọ́júwé,ọwọ́,ó dára,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"b6c8b18c": "Obìnrin tó gún pá",
"g6d10bac": "iyèméjì,àìmọ̀kan,àìnáání,gúnpá,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"b346cd34": "Èyàn tó ń ṣánpá",
"ab290ae6": "àníàní,àìmọ̀kan,àìbìkítà,ṣánpá",
"e963997a": "Ọkùnrin tó gún pá",
"db935aca": "iyèméjì,àìmọ̀kan,aláìnání,gúnpá,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"b09b6cc6": "Obìrin tí inú rẹ dùn tó ngbọ́wọ́ kan sókè",
"e2c2b5a2": "ìfọwọ́júwé,ọwọ́,dunú,nà sóké,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"g8cb6fb0": "Ẹni tí inú rẹ̀ dùn tó tún nna ọwọ́ kan",
"ec80b42a": "ìfarajúwe,ọwọ́,inú dídùn,ti gbé sóké",
"bbbe07d6": "Ọkùnrin tí inú rẹ dùn tó ngbọ́wọ́ kan sókè",
"jb204bd6": "ìfọwọ́júwé,ọwọ́,dunú,ná sókè,ọkùnrin,akọ, àwọn ọkùnrin",
"f0c5fba4": "Obìnrin tó nfi àtẹ́lẹ́ ọwọ́ bojú",
"iaaf2e58": "àìgbàgbọ́,ìkórira,ojú,àtẹ́lẹ́ ọwọ́,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"ae0a4604": "Èyàn tó n fi àtẹ́lẹwọ́ sójú",
"b2231a72": "àníàní,dídálágara,ojú,àtẹlẹwọ́",
"d06b9a8a": "Ọkùnrin tó nfi àtẹ́lẹ́ ọwọ́ bojú",
"geba6516": "àìgbàgbọ́,ìkórira,ojú,àtẹ́lẹ́ ọwọ́,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"g59109da": "Obìrin adití",
"idd2704e": "ìráàyèsí,dití,obìrin,ákọ,àwọn obìrin",
"b6321fbc": "Adití ènìyàn",
"b74cc776": "ìráàyèsí,dití",
"a76c2692": "Ọkùnrin adití",
"cbcf1268": "ìráàyèsí,àdití,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"ba3fc5f8": "Obinrin tó nyọ ẹnu sí wájú",
"a6e3a3be": "ìfọwọ́júwé,ṣu ẹnu síta,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"c1574dcc": "Èyàn tó ń ṣu ẹnu jọ",
"ba9cc92c": "ìfarajúwe,ṣíṣu ẹnu jọ",
"e3dcb2e8": "Ọkùnrin tó nyọ ẹnu sí wájú",
"f0858830": "ìfọwọ́júwé,ṣe ẹnu síta,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"i695b65c": "Obìnrin tó nfajúro",
"a4149182": "rúnjú,ìfarajúwe,banújẹ́,obìrin,abo,àwọn obìrin",
"ad75c008": "Ènìyàn tó nfajúro",
"j36a4b5e": "rúnjú,ìfarajúwe,banújẹ́",
"i30dc18c": "Ọkùnrin tó nfajúro",
"ced6c6de": "rúnjú,ìfarajúwe,banújẹ́,ọkùnrin,abo,àwọn ọkùnrin",
"cfe1f96a": "Obìnrin tó ń gẹrun rẹ̀",
"ia900072": "agẹrun,ẹwà,orí gígẹ̀,iyàrá ìgbàlejò,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"d6df398c": "Èyan tí wọ́n ngérun rẹ̀",
"c0674114": "agẹrun,ẹwà,irun-gígé,pálọ̀",
"ef13897c": "Ọkùnrin tó ń gẹrun rẹ̀",
"acec7fcc": "agẹrun,ẹwà,orí gígẹ̀,iyàrá ìgbàlejò,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"i350cb02": "Obìnrin tó n gba ìfọwọ́pa ojú",
"g960ddf6": "wíwọ́ ara,ibi ìṣerun,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"h4154020": "Èyàn tó n gba wíwọ́ ojú",
"ia5d1e00": "wíwọ́,ibi ìṣerunlóge",
"h0344604": "Ọkùnrin tó gba ìfọwọ́pa ojú",
"e3ff46c6": "wíwọ́ ara,ibi ìṣerun,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"f93b9a30": "Obìnrin olóyún",
"b01b281c": "lóyún,ọmọ ìkókó,obìnrin,abo,àwọn obìnrin,ikùn,wúkún,kún",
"f698788c": "Olóyún",
"a44a14d2": "ikùn,wú,kún,lóyún,ọmọ ìkókó",
"f85e1b80": "Ọkùnrin olóyún",
"d1748790": "ikùn,wú,kún,lóyún,ọmọ ìkókó,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"j49e2c68": "Fífún ọmọ lọ́yàn",
"g3d03f0a": "ọmú,ọmọ ìkókó,ọmọ ọmú,ìyá,ọmọdé,ìtómọ,mílíkì,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"d73df1a0": "Obìrin tó n fún ọmọ lóúnjẹ",
"i362cd6a": "ọmọ kékeré,ọmọ ìkókó,ọmọdé,ìtọ́jú ọmọ,mílíìkì,ìgò,obìrin,abo,àwọn obìrin",
"c218b0d6": "Èyàn tó n fún ọmọ lóúnjẹ",
"ia1500d2": "ọmọ kékeré,ọmọ ìkókó,ọmọdé,ìtọ́jú ọmọ,mílíìkì, ìgò",
"e0ec3608": "Ọkùnrin tó n fún ọmọ lóúnjẹ",
"jb0c823a": "ọmọ kékeré,ọmọ ìkókó,ọmọdé,ìtọ́jú ọmọ,mílíìkì, ìgò,ọkúnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"f292bf96": "Obìrin tó ń kúnlẹ̀",
"h16e8fa0": "kúnlẹ̀,ń kúnlẹ̀,obìrin,abo,àwọn obìrin",
"gbdffe22": "Èyàn tó wà ní ìkúnlẹ̀",
"i0ff5df4": "kúnlẹ̀,ìkúnlẹ̀",
"a1b3744a": "Ọkùnrin tó ń kúnlẹ̀",
"i0cc53aa": "kúnlẹ̀,ń kúnlẹ̀,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"a75ec05a": "Obìrín tó wà ní ìdúró",
"ed80c842": "duró,ndúró,obìrin,abo,àwọn obírin",
"b956a590": "Èyan tó ń dúró",
"h85c9390": "dúró,ní ìdúró",
"d4e8cb72": "Ọkùnrin tó wà ní ìdúró",
"h732c292": "dúró,ndúró,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"fa7f93ea": "Obìnrin tó ń rìn",
"i3eaa8ce": "rínrìn àjò,ibi tí àwọn ẹlẹ́sẹ̀ ma gbà,rìn,ń rìn,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"e9c5860e": "Èyàn tó n rìn",
"a83b7414": "ìrìn,ẹlẹ́sẹ̀,rìn,rirìn",
"cc12650c": "Ọkùnrin tó ń rìn",
"d5fd62ce": "rínrìn àjò,ibi tí àwọn ẹlẹ́sẹ̀ ma gbà,rìn,ń rìn,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"jc72624a": "Obìrin pẹ̀lú ọ̀pá tó ń ṣèwádìí",
"gadd3df8": "ìráàyèsí,fọ́jú,obìrin,abo,àwọn obìrin",
"hd03af72": "Èyàn pẹ̀lú ọ̀pá tó ń ṣèwádìí",
"c5f60d98": "ìráàyèsí,fọ́jú",
"j2168932": "Ọkùnrin pẹ̀lú ọ̀pá tó ń ṣèwádìí",
"a3fc324a": "ìráàyèsí,fọ́jú,ọkùnrin,abo,àwọn ọkùnrin",
"ife8901a": "Obìnrin tó ń saré",
"e17f2518": "eré sísá,olùsáré,ń sáré,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"i744ed88": "Èyàn tó ń sáré",
"b2f75794": "eré ẹlẹ́mìí ẹṣin,eléré,eré-sísá",
"idfadf68": "Ọkùnrin tó ń saré",
"f5127e44": "eré sísá,olùsáré,ń sáré,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"g3a56870": "Obìrin nínu kẹ̀kẹ́ arọ àìfọwọ́yí",
"be36f7f8": "ìráàyèsí,kẹ̀kẹ́ arọ,obìrin,abo,àwọn obìrin",
"a4e52204": "Èyàn nínu kẹ̀kẹ́ arọ àìfọwọ́yí",
"de861316": "ìráàyèsí,kẹ̀kẹ́ arọ ",
"ba505394": "Ọkùnrin nínu kẹ̀kẹ́ arọ àìfọwọ́yí",
"h37c4528": "ìráàyèsí,kẹ̀kẹ́ arọ,ọkùnrin,abo,àwọn ọkùnrin",
"id326a58": "Obìrin nínu kẹ̀kẹ́ arọ àfọwọ́yí",
"e9f6a716": "Èyàn nínu kẹ̀kẹ́ arọ àfọwọ́yí",
"b89703a6": "Ọkùnrin nínu kẹ̀kẹ́ arọ àfọwọ́yí",
"headddfa": "Obìrin tó n jó",
"e65bad22": "jọ́,ń jó,olùjó,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"fe72fe34": "Ọkùnrin tó n jó",
"h418b698": "jó,ń jó,olùjó,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"c182c686": "Àwọn obìnrin tó ní etí ehoro",
"a46b984a": "ọmọ ehoro,olùjó,obìnrin,abo,àwọn obìnrin",
"b84a0b22": "Àwọn èyàn pẹ̀lú etí ehoro",
"h1cdbc1c": "ehoro,oníjó",
"b74e9528": "Àwọn ọkùnrin tó ní etí ehoro",
"b368b790": "ọmọ ehoro,olùjó,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin",
"a6134992": "Obìrin àti ọkùnrin tó n di ọwọ́ mú",
"i0283018": "ọkọ àti ìyàwó,ọwọ́,dìmú,ọkùnrin,obìnrin,abo,àwọn ọkùnrin,àwọn obìnrin",
"f60d9fbe": "Awọn obìrin tó n di ọwọ́ mú",
"e74528e2": "takọtabo,ọwọ́, dìmú, obìrin, arábìrin, áwọn obìrin, ìwúrí, lgbt, obìrin abẹ́yà-kan-náà-lòpọ̀",
"ae7f059e": "Awọn ọkùnrin tó n di ọwọ́ mú",
"c90a718c": "takọtabo,ọwọ́,dìmú, ọkùnrin,akọ,áwọn ọkùnrin,ìwúrí,lgbt,ọkùnrin abẹ́yà-kan-náà-lòpọ̀",
"b7b4fee8": "Àwọn èyàn tó dira wọn lọ́wọ́ mú",
"a6a9a270": "takọtabo,ọwọ́,dìmú",
"ba766984": "Àwọn takọtabo tó ní ọkàn (obìnrin, ọkùnrin)",
"a10dea22": "akọ àti abo,ọkàn,ìfẹ́,ìbálòpọ́,ọkùnrin,obìnrin,akọ,abo,àwọn ọkùnrin,àwọn obìnrin",
"a6669472": "Àwọn takọtabo tó ní ọkàn (obìnrin, obìnrin)",
"b66b04ae": "takọtabo,ọkàn,ìfẹ́,ọ̀rọ̀-ifẹ́,obìrin,abo,àwọn obìrin,ìwúrí, lgbt,obìrin abẹ́yà-kan-náà-lòpọ̀",
"d0b17cc4": "Takọtabo pẹ̀lú ọkàn",
"jfa23ebe": "Àwọn takọtabo tó ní ọkàn (ọkùnrin, ọkùnrin)",
"ffe564b8": "takọtabo,ọkàn,ìfẹ́, ọ̀rọ̀-ifẹ́,ọkùnrin,abo,àwọn ọkùnrin,ìwúrí,lgbt,ọkùnrin abẹ́yà-kan-náà-lòpọ̀",
"a043448c": "Fi ẹnu ko (obìnrin, ọkùnrin) lẹ́nu",
"c8510f84": "akọ àti abo,fi ẹnu ko ẹnu,ọkàn,ìfẹ́,ìbálòpọ̀,ọkùnrin,obìnrin,akọ,abo,àwọn ọkùnrin,àwọn obìnrin",
"b3404010": "Fi ẹnu ko (obìnrin, obìnrin) lẹ́nu",
"cf3c4280": "takọtabo,fẹnukẹnu,ọkàn,ìfẹ́,ọ̀rọ̀-ifẹ́,obìrin,abo,àwọn obìrin,ìwúrí, lgbt,obìrin abẹ́yà-kan-náà-lòpọ̀",
"dc47f49c": "Ìfẹnukonu",
"j482d68a": "Fi ẹnu ko (ọkùnrin, ọkùnrin) lẹ́nu",
"bc20e3ec": "takọtabo,fẹnukẹnu,ọkàn,ìfẹ́,ọ̀rọ̀-ifẹ́,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin,ìwúrí,lgbt,ọkùnrin abẹ́yà-kan-náà-lòpọ̀",
"da5b545c": "Mọ̀lẹ́bí",
"ade693f2": "mọ̀lẹ́bí,bàbá,ìyá,ọkùnrin,obìnrin,akọ,abo,àwọn ọkùnrin,àwọn obìnrin,ọmọdékùnrin,ọmọdé",
"c894fc82": "Mọ̀lẹ́bí (ọkùnrin, obìnrin, ọmọdébìnrin)",
"bfa0ec6c": "mọ̀lẹ́bí,bàbá,ìyá,ọkùnrin,obìnrin,akọ,abo,àwọn ọkùnrin,àwọn obìnrin,ọmodékùnrin,ọmodébìnrin,ọmodé",
"bad60942": "Mọ̀lẹ́bí (ọkùnrin, obìnrin, ọmọdébìnrin, ọmọdékùnrin)",
"b4b6eea4": "mọ̀lẹ́bí,bàbá,ìyá,ọkùnrin,obìnrin,akọ,abo,àwọn ọkùnrin,àwọn obìnrin,ọmọdékùnrin,ọmodébìnrin,ọmodé",
"gf62a6fc": "Mọ̀lẹ́bí (ọkùnrin, obìnrin, ọmọdékùnrin, ọmọdékùnrin)",
"db063eb0": "Mọ̀lẹ́bí (ọkùnrin, obìnrin, ọmọdébìnrin, ọmọdébìnrin)",
"hf26249c": "mọ̀lẹ́bí,bàbá,ìyá,ọkùnrin,obìnrin,akọ,abo,àwọn ọkùnrin,àwọn obìnrin,ọmodébìnrin,ọmodé",
"c18c7540": "Mọ̀lẹ́bí (obìnrin, obìnrin, ọmọdékùnrin)",
"bd5ed686": "ẹbí,ìyá, bìrin,abo,àwọn obìrin,ọmọdékùnrin,ọmọdé,ìwúrí,lgbt,obìrin abẹ́yà-kan-náà-lòpọ̀",
"i75fa05c": "Mọ̀lẹ́bí (obìnrin, obìnrin, ọmọdébìnrin)",
"i5b25176": "ẹbí,ìyá,obìrin,abo,àwọn obìrin,ọmọdébìrin,ọmọdé,ìwúrí,lgbt,obìrin abẹ́yà-kan-náà-lòpọ̀",
"ead40d62": "Mọ̀lẹ́bí (obìnrin, obìnrin, ọmọdébìnrin, ọmọdékùnrin)",
"gffcd2f0": "ẹbí,ìyá,obìrin,abo,àwọn obìrin,ọmọdékùnrin,ọmọdébìrin,ọmọdé,ìwúrí,lgbt,obìrin abẹ́yà-kan-náà-lòpọ̀",
"jc7cd188": "Mọ̀lẹ́bí (obìnrin, obìnrin, ọmọdékùnrin, ọmọdékùnrin)",
"e684d50a": "Mọ̀lẹ́bí (obìnrin, obìnrin, ọmọdébìnrin, ọmọdébìnrin)",
"i65bd7f2": "Mọ̀lẹ́bí (ọkùnrin, ọkùnrin, ọmọdékùnrin)",
"ea7e5b32": "ẹbí,bàbá,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin,ọmọdékùnrin,ọmọdé,ìwúrí,lgbt,ọkùnrin abẹ́yà-kan-náà-lòpọ̀",
"b81493f0": "Mọ̀lẹ́bí (ọkùnrin, ọkùnrin ọmọdébìnrin)",
"j5976d90": "ẹbí,bàbá,ọkùnrin,abo,àwọn ọkùnrin,ọmọdébìrin,ọmọdé,ìwúrí,lgbt,ọkùnrin abẹ́yà-kan-náà-lòpọ̀",
"fa4cfbc2": "Mọ̀lẹ́bí (ọkùnrin, ọkùnrin, ọmọdébìnrin, ọmọdékùnrin)",
"c5ce037c": "ẹbí,bàbá,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin,ọmọdékùnrin,ọmọdébìrin,ọmọdé,ìwúrí,lgbt, ọkùnrin abẹ́yà-kan-náà-lòpọ̀",
"e3fb2680": "Mọ̀lẹ́bí (ọkùnrin, ọkùnrin, ọmọdékùnrin, ọmọdékùnrin)",
"ab31c920": "Mọ̀lẹ́bí (ọkùnrin, ọkùnrin, ọmọdébìnrin, ọmọdébìnrin)",
"h63e67a0": "Mọ̀lẹ́bí (obìnrin, ọmọdékùnrin)",
"c095d06c": "mọ̀lẹ́bí,ìyà,obìnrin,abo,àwọn obìnrin,ọmọdékùnrin,ọmọdé",
"j1022956": "Mọ̀lẹ́bí (obìnrin, ọmọdébìnrin)",
"hf684d84": "mọ̀lẹ́bí,ìyà,obìnrin,abo,àwọn obìnrin,ọmọdé",
"b2b7b5fe": "Mọ̀lẹ́bí (obìnrin, ọmọdébìnrin, ọmọdékùnrin)",
"h7870dde": "mọ̀lẹ́bí,ìyà,obìnrin,abo,akọ,obìnrin,ọmọdékùnrin,ọmọdé",
"b66a56bc": "Mọ̀lẹ́bí (obìnrin, ọmọdékùnrin, ọmọdékùnrin)",
"i0b8ae16": "Mọ̀lẹ́bí (obìnrin, ọmọdébìnrin, ọmọdébìnrin)",
"efd8405a": "Mọ̀lẹ́bí (ọkùnrin, ọmọdékùnrin)",
"ic8e6f86": "mọ̀lẹ́bí,bàbá,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin,ọmọdékùnrin,ọmọdé",
"ibafc678": "Mọ̀lẹ́bí (ọkùnrin, ọmọdébìnrin)",
"j24dbc3c": "mọ̀lẹ́bí,bàbá,ọkùnrin,akọ,abo,ọmọdébìnrin,ọmọdé",
"c7583f7c": "Mọ̀lẹ́bí (ọkùnrin, ọmọdébìnrin, ọmọdékùnrin)",
"c84e5252": "mọ̀lẹ́bí,bàbá,ọkùnrin,akọ,àwọn ọkùnrin,ọmọdékùnrin,ọmọdébìnrin,ọmọdé",
"e8116c9a": "Mọ̀lẹ́bí (ọkùnrin, ọmọdékùnrin, ọmọdékùnrin)",
"da82afda": "Mọ̀lẹ́bí (ọkùnrin, ọmọdébìnrin, ọmọdébìnrin)",
"fffba828": "Aṣọ obìrin",
"c487e340": "aṣọ,obìnrin",
"b3227ba8": "Tí-ṣẹ́ẹ̀tì",
"jc592522": "aṣọ,ṣẹ́ẹ̀tì,t-ṣẹ́ẹ̀tì",
"ff1dec08": "Ẹ̀wù laabù",
"e392f624": "aṣọ,dókítà,ìdánwò,oní ìmọ̀ sáyẹ́nsì",
"ff25387e": "Bùbá àbò",
"i1344a8a": "pàjáwìrì,ààbò,fẹ́sìtì",
"h31fc21a": "Ẹ̀wù",
"f3bcd1b6": "aṣọ,ẹ̀wù,aṣọ pénpé ",
"e13073ae": "Jíìnsì",
"db4c7cb2": "aṣọ,jíìnsì,pátá,ṣòkòtò",
"f7a5dba0": "Okùn ọrùn àwọn ọkùnrin",
"e02af70c": "aṣọ,ìso sẹ́ẹ̀tì lọ́rùn",
"cf63aa14": "Aṣọ",
"cd5504c4": "aṣọ, aṣọ wíwọ̀",
"ia47418e": "Kìmónò",
"fff5f6a2": "aṣọ,kimono",
"b6e54dd8": "Sari",
"f022173e": "aṣọ,ẹ̀wù,sari",
"fdf6f8f2": "Abala kan",
"b4085daa": "aṣọ,aṣọ-ìwẹ̀,aṣọ-ìlùwẹ̀,wíwẹ̀",
"bc802e4a": "Bìkínì",
"i01f8ce2": "bikini,aṣọ,lùwẹ",
"b25971fe": "Aṣọ pélébé",
"e7125100": "aṣọ,aṣọ-ìwẹ̀,aṣọ-ìlùwẹ̀,wẹ̀,ṣòkòtò kékeré ọkùnrin,aṣọ àwọ̀tẹ́lẹ̀",
"c12d8c98": "Ṣòkòtò kékeré",
"a9cfb608": "aṣọ,aṣọ-ìwẹ̀,aṣọ-ìlùwẹ̀, wíwẹ̀,ṣòkòtò kékeré ọkùnrin,aṣọ àwọ̀tẹ́lẹ̀",
"if14c6c0": "Ìtọ́tè",
"cc0a345a": "èròjà aṣaralóge,,ìtọ́tè,aṣojú lóge",
"af6648dc": "Àmì ìfẹnukonu",
"c4a7603a": "ọkàn,fi ẹnu ko ẹnu,ètè,ṣàmì,ìbálòpọ̀",
"ja70abee": "Àwọn àpá ẹsẹ̀",
"jfcc2cfa": "ara,aṣọ,ojú ẹsẹ̀,ṣàtẹ̀jáde",
"e711e7cc": "Ìbọ̀sẹ̀",
"df9653b8": "aṣọ,ìbọsẹ̀,méjì",
"ecd95bac": "Bàtà olókùn",
"a8298b4e": "etí òkun,sálúbàtà,awọ tẹ́ẹ́rẹ́,bàtà ilẹ japan",
"b9d2a3e6": "Bàtà gíga",
"b3c2540e": "aṣọ,bàtà gíga,bàtà,obìnrin",
"fc8a8084": "Bàtà obìrin",
"hcac4594": "aṣọ,bàtà pẹlẹbẹ,bàtà,obìnrin",
"f9db3e7c": "Búùtù obìrin",
"e6c786c4": "buutù,aṣọ,bàtà,obìnrin",
"aaaa9174": "Bàtà pẹlẹbẹ obìrin",
"b33bfb96": "aṣọ,bàtà bàlé,bàtà pẹlẹbẹ,bàtà àtẹsẹ̀bò",
"e208fb56": "Bàtà ọkùnrin",
"h3d298da": "aṣọ,ọkùnrin,bàtà",
"gccf6c8e": "Bàtà ìsáré",
"c934b9ca": "eré sísá,aṣọ,bàtà,bàtà olókùn",
"i9082f14": "Bàtà bàlé",
"h469885a": "aṣọ,bàtà,bàlé,ijó",
"bb183e24": "Bútù ìrìn ìgbẹ̀fẹ̀",
"i64b8e70": "aṣọ,ìrìn ájò afẹ́,búùtì,pípàgọ́,ìrìn àrìnwọ́dìí",
"fdb6cdd4": "Gbèndéke tí a díyelé",
"a6d38652": "aṣọ,besbọọlù,fìlà,àkẹtẹ̀",
"e80b978c": "Fìlà obìrin",
"cab04f0a": "aṣọ,fìlà,obìnrin",
"ga357e16": "Ate",
"a0ad4c3c": "ìṣẹ́ ṣíṣe,aṣọ,ìdárayá,fìlà,aṣọ òkè,fílá ",
"e603d6e0": "Fìlà ìkẹ́kọ̀ọ́ gboyè",
"d9ff2c1a": "ìṣẹ́ ṣíṣe,fìlá,àjọyọ̀,ìkẹ́kọ̀ọ́ gboyè,fìlà",
"i38dde22": "Adé",
"dc33eb3c": "aṣọ,adé,ọba,olorì",
"bbf7fa1a": "Akoto ìborí tó ní àgbélébùú funfun",
"b2573e8c": "ìrànwọ́,àgbélébùú,ojú,fìlà,akoto ìdérí",
"fef0cace": "Akoto ológun",
"e39d42de": "ológun,akoto,ti ologun,jagunjagun,akọni",
"d6968994": "Báàgì ilé ìwé",
"id8fbf34": "iṣẹ́ ṣíṣe,apamọ́wọ́,àpò,ilé ìwé",
"b037edbe": "Àpò ìléwọ́",
"e09d5476": "apamọ́wọ́,aṣọ,àpò ìléwọ́",
"afbb2e12": "Pọ́ọ̀sì",
"addf1adc": "aṣọ,owó ẹyọ,pọ́ọ̀sì",
"d5d2944c": "Àpámọ́wọ́",
"e963e0ea": "apamọ́wọ́,aṣọ,àpò ọlọ́wọ́",
"d438dff2": "Àpótí ìwé",
"b376735e": "àpótí ìwé",
"g3d2ead6": "Awò ojú",
"a935b160": "aṣọ,ojú,awò ojú,igo ojú,ìgo ojú",
"ee98c8fc": "Awò ojú dúdú",
"c18c17fa": "dúdú,ojú,ìgò ojú,ìgò,ìgò ojú",
"ad7eee7a": "Awò ojú ",
"c45f63b6": "aṣọ,ìdáàbòbò ojú,wíwẹ̀, irin-jíjó",
"f9297e14": "Ìborùn",
"h42e6090": "aṣọ,ìborùn,ọrùn",
"fc29a6c0": "Ìbọ̀wọ́",
"gf3b0f34": "aṣọ,àwọn ìbọ̀wọ́,ọwọ́",
"jca5d650": "Òrùka",
"h5d7c5a4": "díámọ́ndì,òrùka,ìbálòpọ̀",
"d2cdebc4": "Agboòrùn tó padé",
"f6216052": "aṣọ,òjò,agboòrùn,ojú ọjọ́",
"d2a77abe": "Agboòrùn",
"cd0838ca": "Ojú ajá",
"b3b58b66": "ajá,ojú,ohun ọ̀sìn",
"caac33a2": "Ojú ológbò",
"e4863eea": "ológbò,ojú,ohun ọ̀sìn",
"dae24724": "Ojú eku",
"e72509cc": "ojú,eku",
"c655aa34": "Ojú asín",
"b7b62216": "ojú,eku ńlá,ohun ọ̀sìn",
"c191d34c": "Ojú ehoro",
"a04b2d5a": "ehoro,ojú,ohun ọ̀sìn,ehoro",
"afd26148": "Ojú Bearì",
"e1595fea": "beari,ojú",
"i7d9d672": "Àtọwọ́dá béárì",
"d39072ce": "ǹkan eré,aṣọ,ti ṣùpọ̀,ǹkan ìṣeré",
"i8aa3e54": "Ojú Pandà",
"b5ccf0c4": "ojú,pándà,bíárì",
"b5f48912": "Àwọn ẹranko ńlá ilẹ̀ olótùútù",
"b4e85792": "oju,ilẹ̀ olótútù,ẹranko bíárì,funfun",
"cd04c022": "Koala",
"b47d991c": "bíárì,kòálà,mársùpíá,australia",
"d1845ca4": "Ojú ẹkùn",
"bd1f6138": "oju,ẹkùn",
"i43d669a": "Ojú kìnìún",
"d2419ab4": "ojú,leo,kìnìún,akọsẹ̀jayé",
"dec4799a": "Ojú màlúù",
"d2987728": "màálù,ojú",
"c7e5aaa4": "Ojú ẹlẹ́dẹ̀",
"ia8e2a44": "ojú,ẹlẹ́dẹ̀",
"eb09c104": "Imú ẹlẹ́dẹ̀",
"d1debd7c": "ojú,imu,ẹlẹ́dẹ̀",
"e2b5bdf2": "Ojú ọ̀pọ̀lọ́",
"a3f5f7cc": "ojú,kọ̀nkọ̀",
"ffb39478": "Ojú ọ̀bọ",
"j99b7f54": "ojú,ọ̀bọ",
"a45f4356": "Ọbọ tí kò fẹ́ rí ibi",
"d86cbf58": "burú,ojú,èèwọ̀,ìfọwọ́júwé,ọ̀bọ,bẹ́ẹ̀kọ́,rárá,èèwọ̀,wò",
"da825ca4": "Ọbọ tí kò fẹ́ gbọ́ ibi",
"a9a2506e": "burú,ojú,èèwọ̀,ìfọwọ́júwè.gbọ́,ọ̀bọ,bẹ́ẹ̀kọ́,rárá,èèwọ̀",
"f38be7a2": "Ọbọ tí kò fẹ́ sọ ibi",
"e07f08fe": "burú,ojú,èèwọ̀,ìfọwọ́júwé,ọ̀bọ,bẹ́ẹ̀kọ́,rárá,èèwọ̀,sọ̀rọ̀",
"a5351fd6": "Ọbọ",
"c9de0686": "ọ̀bọ",
"d343139a": "Ìnàkí",
"haf110b0": "ìnàkí",